2 Sámúẹ́lì 14:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
“Ǹjẹ́ nítorí náà ni èmi sì ṣe wá sọ nǹkan yìí fún Olúwa mi ọba, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn ti dẹ́rùbà mí; ìránṣẹ́bìnrin rẹ sì wí pé, ‘Ǹjẹ́ èmi ó sọ fún ọba; ó lè rí bẹ́ẹ̀ pé ọba yóò ṣe ìfẹ́ ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ fún un.