Áhásì sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ ní ìlú Dáfídì: Heṣekáyà ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.