Àwọn ọmọ, Húṣì:Ísíráhíà.Àwọn ọmọ Ísíráhíà:Míkáélì Ọbádáyà, Jóẹ́lì àti Ísíhíáhì. Gbogbo àwọn máràrùn sì jẹ́ olóyè.